2 Sámúẹ́lì 18:33 BMY

33 Ọba sì kẹ́dùn púpọ̀ ó sì gòkè lọ, sí yàrá tí ó wà lórí òkè ibodè, ó sì sunkún; bayìí ni ó sì ń wí bí ó ti ń lọ, “Ọmọ mi Ábúsálómù! Ọmọ mi! Ọmọ mí Ábúsálómù! Áì! Ìbáṣepé èmi ni ó kú ní ipò rẹ̀! Ábúsálómù ọmọ mi, ọmọ mi!”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 18

Wo 2 Sámúẹ́lì 18:33 ni o tọ