2 Sámúẹ́lì 19:19 BMY

19 Ó sì wí fún ọba pé, “Kí Olúwa mi ó má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ sí mi lọ́rùn, má sì ṣe rántí àfojúdi tí ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣe ni ọjọ́ tí Olúwa mi ọba jáde ní Jérúsálẹ́mù, kí ọba má sì fi sí inú.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:19 ni o tọ