2 Sámúẹ́lì 19:26 BMY

26 Òun sì dáhùn wí pé, “Olúwa mi, Ọba, ìránṣẹ́ mi ni ó tàn mí, nítorí ìránṣẹ́ rẹ wí fún un pé, ‘Di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ní gàárì fún mi èmi ó gùn ún, èmi ó sì tọ ọba lọ.’ Nítorí tí ìránṣẹ́ rẹ yarọ.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:26 ni o tọ