2 Sámúẹ́lì 19:3 BMY

3 Àwọn ènìyàn náà sì yọ́ lọ sí ìlú ní ijọ́ náà gẹ́gẹ́ bí àwọn bí ènìyàn tí a dójútì ṣe máa ń yọ́ lọ nígbà tí wọ́n bá sá lójú ìjà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:3 ni o tọ