2 Sámúẹ́lì 19:31 BMY

31 Básíláì ará Gílíádì sì sọ̀kalẹ̀ láti Rogelímù wá, ó sì bá ọba gòkè odò Jódánì, láti ṣe ìkẹ́ rẹ̀ sí ìkọjá odò Jódánì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:31 ni o tọ