2 Sámúẹ́lì 19:33 BMY

33 Ọba sì wí fún Básíláì pé, “Ìwọ wá bá mi gòkè odò, èmi ó sì máa pésè fún ọ ní Jérúsálẹ́mù.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 19

Wo 2 Sámúẹ́lì 19:33 ni o tọ