2 Sámúẹ́lì 2:1 BMY

1 Lẹ́yìn àkókò yìí, Dáfídì wádìí lọ́wọ́ Olúwa. Ó sì béèrè pé, “Ṣé èmi lè gòkè lọ sí ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Olúwa sì wí pé, “Gòkè lọ.”Dáfídì sì béèrè pé, “Ní ibo ni kí èmi kí ó lọ?” Olúwa sì dáa lóhùn pé, “Sí Hébúrónì.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 2

Wo 2 Sámúẹ́lì 2:1 ni o tọ