2 Sámúẹ́lì 2:14 BMY

14 Nígbà náà, Ábínérì sọ fún Jóábù pé, “Jẹ́ kí díẹ̀ nínú àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yìí ó dìde láti bá ara wọn jà níwájú wa.”Jóábù sì dáhùn pé, “Ó dára, jẹ́ kí wọ́n ṣe é,”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 2

Wo 2 Sámúẹ́lì 2:14 ni o tọ