2 Sámúẹ́lì 21:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n Ábíṣáì ọmọ Sérúíà ràn án lọ́wọ́, ó sì kọlu Fílístínì náà, ó sì paá, Nígbà náà ni àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì sì búra fún un pé, “Ìwọ kì yóò sì tún bá wa jáde lọ sí ibi ìjà mọ́ kí iwọ má ṣe pa iná Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 21

Wo 2 Sámúẹ́lì 21:17 ni o tọ