2 Sámúẹ́lì 23:1 BMY

1 Wọ̀nyí sì ni ọ̀rọ̀ ìkẹyìn Dáfídì.“Dáfídì ọmọ Jésè,àní ọkùnrin tí a ti gbéga,ẹni-àmì òróró Ọlọ́run Jákọ́bù,àti olórin dídùn Ísírẹ́lì wí pé:

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 23

Wo 2 Sámúẹ́lì 23:1 ni o tọ