2 Sámúẹ́lì 23:10 BMY

10 Òun sì dìde, ó sì kọlu àwọn Fílístínì títí ọwọ́ fi kún un, ọwọ́ rẹ̀ sì lẹ̀ mọ́ idà; Olúwa sì ṣiṣẹ́ ìgbàlà ńlá lọ́jọ́ náà, àwọn ènìyàn sì padà bọ̀ lẹ́yìn rẹ̀ láti kó ìkógun.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 23

Wo 2 Sámúẹ́lì 23:10 ni o tọ