2 Sámúẹ́lì 23:13 BMY

13 Àwọn mẹ́ta nínú ọgbọ̀n olórí sì sọkalẹ̀, wọ́n sì tọ Dáfídì wá ní àkókò ìkórè nínú ihò Ádúlámù: ọ̀wọ́ àwọn Fílístínì sì dó sí àfonífojì Réfáímù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 23

Wo 2 Sámúẹ́lì 23:13 ni o tọ