2 Sámúẹ́lì 23:19 BMY

19 Ọlọ́lá jùlọ ni òun jẹ́ nínú àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta: ó sì jẹ́ olórí fún wọn: ṣùgbọ́n òun kò tó àwọn mẹ́ta ìṣáájú.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 23

Wo 2 Sámúẹ́lì 23:19 ni o tọ