2 Sámúẹ́lì 24:18 BMY

18 Gádì sì tọ Dáfídì wá lọ́jọ́ náà, ó sì wí fún un pé, “Gòkè, tẹ́ pẹpẹ kan fún Olúwa níbi ìpakà Áráúnà ará Jébúsì.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:18 ni o tọ