2 Sámúẹ́lì 24:22 BMY

22 Áráúnà sì wí fún Dáfídì pé, “Jẹ́ kí Olúwa mi ọba ó mú èyí tí ó dára lójú rẹ̀, kí o sì fi í rúbọ: wò ó, màlúù nìyìí láti fi ṣe ẹbọ sísun, àti ohun èlò ìpakà, àti ohun èlò mìíràn ti màlúù fún igi.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 24

Wo 2 Sámúẹ́lì 24:22 ni o tọ