2 Sámúẹ́lì 3:1 BMY

1 Ogun náà sì pẹ́ títí láàrin ìdílé Ṣọ́ọ̀lù àti ìdílé Dáfídì: agbára Dáfídì sì ń pọ̀ si i, ṣùgbọ́n ìdílé Ṣọ́ọ̀lù ń rẹ̀yìn si i.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 3

Wo 2 Sámúẹ́lì 3:1 ni o tọ