2 Sámúẹ́lì 3:20 BMY

20 Ábínérì sì tọ Dáfídì wá ní Hébírónì, ogún ọmọkùnrin sì lọ pẹ̀lú rẹ̀ Dáfídì sì se àsè fún Ábínérì àti fún àwọn ọmọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 3

Wo 2 Sámúẹ́lì 3:20 ni o tọ