2 Sámúẹ́lì 3:32 BMY

32 Wọ́n sì sin Ábínérì ní Hébírónì: ọba sì gbé ohùn rẹ̀ sókè, ó sì sunkùn ní ibojì Ábínérì; gbogbo àwọn ènìyàn náà sì sunkún.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 3

Wo 2 Sámúẹ́lì 3:32 ni o tọ