2 Sámúẹ́lì 3:7 BMY

7 Ṣọ́ọ̀lù ti ní àlè kan, orúkọ rẹ̀ sì ń jẹ́ Rísípà, ọmọbínrin Áíyà: Íṣíbóṣétì sì bi Ábínérì léèrè pé, “Èéṣe tí ìwọ fi wọlé tọ àlè baba mi lọ.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 3

Wo 2 Sámúẹ́lì 3:7 ni o tọ