2 Sámúẹ́lì 5:22 BMY

22 Àwọn Fílístínì sì tún gòkè wá, wọ́n sì tan ara wọn kalẹ̀ ní àfonífojì Rafaímù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 5

Wo 2 Sámúẹ́lì 5:22 ni o tọ