2 Sámúẹ́lì 5:3 BMY

3 Gbogbo àgbà Ísírẹ́lì sì tọ ọba wá ní Hébírónì, Dáfídì ọba sì bá wọn ṣe àdéhùn kan ní Hébírónì, níwájú Olúwa: wọ́n sì fi òróró yan Dáfídì ní ọba Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 5

Wo 2 Sámúẹ́lì 5:3 ni o tọ