2 Sámúẹ́lì 5:9 BMY

9 Dáfídì sì jókòó ní ilé àwọn ọmọ ogun tí ó ní odi, a sì ń pè é ní ìlú Dáfídì. Dáfídì mọ ìgànná yí i ká láti Mílò wá, ó sì kọ́ ilé nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 5

Wo 2 Sámúẹ́lì 5:9 ni o tọ