2 Sámúẹ́lì 6:13 BMY

13 Ó sì ṣe nígbà tí àwọn ènìyàn tí ó ru àpótí-ẹ̀rí Olúwa bá sì ṣí ẹsẹ̀ mẹ́fà, òun a sì fi màlúù àti ẹran àbọ́pa rúbọ.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 6

Wo 2 Sámúẹ́lì 6:13 ni o tọ