2 Sámúẹ́lì 6:15 BMY

15 Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì àti gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì gbé àpótí-ẹ̀rí Olúwa gòkè wá, pẹ̀lú ìhó ayọ̀, àti pẹ̀lú ìró ìpè.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 6

Wo 2 Sámúẹ́lì 6:15 ni o tọ