2 Sámúẹ́lì 6:17 BMY

17 Wọ́n sì mú àpótí-ẹ̀rí Olúwa náà wá, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sípò rẹ̀ láàrin àgọ́ náà tí Dáfídì pa fún un: Dáfídì sì rubọ́ sísun àti ẹbọ ìrẹ́pọ̀ níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 6

Wo 2 Sámúẹ́lì 6:17 ni o tọ