2 Sámúẹ́lì 6:21 BMY

21 Dáfídì sì wí fún Míkálì pé, “Níwájú Olúwa ni, ẹni tí ó yàn mí fẹ́ ju baba rẹ lọ, àti ju gbogbo ìdílé rẹ lọ, láti fi èmi ṣe olórí àwọn ènìyàn Olúwa, àní lórí Ísírẹ́lì, èmi ó sì ṣúre níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 6

Wo 2 Sámúẹ́lì 6:21 ni o tọ