2 Sámúẹ́lì 7:21 BMY

21 Nítorí ọ̀rọ̀ rẹ, àti gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ ọkàn rẹ, ni ìwọ ṣe ṣe gbogbo nǹkan ńlá wọ̀nyí, kí ìránṣẹ́ rẹ lè mọ̀.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:21 ni o tọ