2 Sámúẹ́lì 7:27 BMY

27 “Nítorí pé ìwọ, Olúwa àwọn ọmọ-ogún, Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti sọ létí ìránṣẹ́ rẹ, pé, ‘Èmí ó kọ́ ilé kan fún ọ.’ Nítorí náà ni ìránṣẹ́ rẹ sì ṣe ní i lọ́kàn rẹ̀ láti gbàdúrà yìí sí ọ.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 7

Wo 2 Sámúẹ́lì 7:27 ni o tọ