2 Sámúẹ́lì 9:12 BMY

12 Méfibóṣétì sì ní ọmọ kékeré kan, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Míkà. Gbogbo àwọn tí ń gbé ní ilé Síbà ni ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún Méfibóṣétì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 9

Wo 2 Sámúẹ́lì 9:12 ni o tọ