2 Sámúẹ́lì 9:3 BMY

3 Ọba sì wí pé, “Kò ha sí ọ̀kan nínú ìdílé Ṣọ́ọ̀lù ṣíbẹ̀, kí èmi ṣe ooré Ọlọ́run fún un?”Ṣíbà sì wí fún ọba pé, “Jónátanì ní ọmọ kan ṣíbẹ̀ tó ya arọ.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 9

Wo 2 Sámúẹ́lì 9:3 ni o tọ