Oníwàásù 10:1 BMY

1 Gẹ́gẹ́ bí òkú eṣinṣin tí ń fún ìpara ní òórùn burúkú,bẹ́ẹ̀ náà ni òmùgọ̀ díẹ̀ ṣe ń bo ọgbọ́n àti ọlá mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Oníwàásù 10

Wo Oníwàásù 10:1 ni o tọ