Oníwàásù 10:9 BMY

9 Ẹnikẹ́ni tí ó bá pe òkúta lẹ́jọ́ le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn;ẹnikẹ́ni tí ó bá la ìtì-igi le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Oníwàásù 10

Wo Oníwàásù 10:9 ni o tọ