Oníwàásù 11:5 BMY

5 Gẹ́gẹ́ bí ìwọ kò ti ṣe mọ ojú ọ̀nà afẹ́fẹ́tàbí mọ bí ara tí ń dàgbà nínú ikùn ìyáarẹ̀,bẹ́ẹ̀ náà ni ìwọ kò le è ní òye iṣẹ́ Ọlọ́runẹlẹ́dàá ohun-gbogbo.

Ka pipe ipin Oníwàásù 11

Wo Oníwàásù 11:5 ni o tọ