Oníwàásù 11:9 BMY

9 Jẹ́ kí inú rẹ dùn, ìwọ ọ̀dọ́mọdé ní ìgbà tí o wà ní èwekí o sì jẹ́ kí ọkàn rẹ fún ọ ní ayọ̀ ní ìgbà èwe rẹ.Tẹ̀lé ọ̀nà ọkàn rẹàti ohunkóhun tí ojú rẹ ríṣùgbọ́n mọ̀ dájú pé nípa gbogbo nǹkan wọ̀nyí niỌlọ́run yóò mú ọ wá sí ìdájọ́.

Ka pipe ipin Oníwàásù 11

Wo Oníwàásù 11:9 ni o tọ