Oníwàásù 12:1 BMY

1 Rántí Ẹlẹ́dàá rẹní ọjọ́ èwe rẹ,nígbà tí ọjọ́ ibi kò tíì déàti tí ọdún kò tíì ní ṣun mọ́ etílé, nígbà tí ìwọ yóò wí pé,“Èmi kò ní ìdùnnú nínú wọn”

Ka pipe ipin Oníwàásù 12

Wo Oníwàásù 12:1 ni o tọ