Oníwàásù 12:4 BMY

4 Nígbà tí ilẹ̀kùn sí ìgboro yóò tìtí ariwo ọlọ yóò dákẹ́;nígbà tí àwọn ènìyàn yóò dìde sí ariwo àwọn ẹyẹṣùgbọ́n gbogbo orin wọn yóò máa lọ ilẹ̀.

Ka pipe ipin Oníwàásù 12

Wo Oníwàásù 12:4 ni o tọ