Oníwàásù 5:11 BMY

11 Bí ẹrù bá ti ń pọ̀ síináà ni àwọn tí ó ń jẹ ẹ́ yóò máa pọ̀ síiÈrè e kí ni wọ́n sì jẹ́ sí oní nǹkanbí kò se pé, kí ó máa mú inú ara rẹ dùn nípa rírí wọn?

Ka pipe ipin Oníwàásù 5

Wo Oníwàásù 5:11 ni o tọ