Oníwàásù 7:25 BMY

25 Mó wá ròó nínú ọkàn mi láti mọ̀,láti wá àti láti ṣàwárí ọgbọ́nàti ìdí ohun gbogbo, àti láti mọ àgọ́ ìwàbúburú àti ti ìsínwín tàbí òmùgọ̀.

Ka pipe ipin Oníwàásù 7

Wo Oníwàásù 7:25 ni o tọ