Oníwàásù 8:8 BMY

8 Kò sí ẹni tí ó lágbára lórí afẹ́fẹ́ láti gbàá dúrónítorí náà, kò sí ẹni tí ó ní agbára lórí ọjọ́ ikú rẹ̀.Bí ó ti jẹ́ wí pé kò sí ẹni tí a dá sílẹ̀ nígbà ogun,bẹ́ẹ̀ náà ni ìkà kò ní fi àwọn tí ó ń ṣe é sílẹ̀;bí ó ti jẹ́ wí pé kò sí ẹni tí a dá sílẹ̀ nígbà ogun,bẹ́ẹ̀ náà ni ìfà kò ní fi àwọn tí ó ń ṣe é sílẹ̀.

Ka pipe ipin Oníwàásù 8

Wo Oníwàásù 8:8 ni o tọ