Oníwàásù 9:10 BMY

10 Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, ṣeé pẹ̀lú gbogbo agbára rẹ, nítorí kò sí iṣẹ́ ṣíṣe tàbí ìpinnu tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n nínú iṣà-òkú níbi tí ò ń lọ.

Ka pipe ipin Oníwàásù 9

Wo Oníwàásù 9:10 ni o tọ