Àwọn Ọba Keji 1:10 BM

10 Elija sì dáhùn pé, “Bí mo bá jẹ́ eniyan Ọlọrun, kí iná wá láti ọ̀run, kí ó sì jó ìwọ ati àwọn aadọta ọmọ ogun rẹ!” Lẹ́sẹ̀kan náà, iná wá láti ọ̀run, ó sì jó ọ̀gágun náà ati gbogbo àwọn ọmọ-ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:10 ni o tọ