Àwọn Ọba Keji 1:11 BM

11 Ọba bá tún rán ọ̀gágun mìíràn ati àwọn aadọta ọmọ-ogun rẹ̀ láti lọ mú Elija. Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ Elija òun náà tún sọ fún un pé, “Ìwọ eniyan Ọlọrun, ọba sọ pé kí o sọ̀kalẹ̀ wá kíákíá.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:11 ni o tọ