Àwọn Ọba Keji 1:12 BM

12 Elija tún dáhùn pé, “Bí mo bá jẹ́ eniyan Ọlọrun, kí iná wá láti ọ̀run, kí ó sì jó ìwọ ati àwọn aadọta ọmọ ogun rẹ!” Lẹ́sẹ̀ kan náà, iná wá láti ọ̀run, ó sì jó ọ̀gágun náà ati gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:12 ni o tọ