Àwọn Ọba Keji 10:11 BM

11 Jehu pa gbogbo àwọn ìbátan Ahabu tí wọn ń gbé Jesireeli ati àwọn iranṣẹ rẹ̀, ati àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ati àwọn alufaa; kò dá ọ̀kan ninu wọn sí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:11 ni o tọ