Àwọn Ọba Keji 10:10 BM

10 Èyí fihàn dájú pé gbogbo ohun tí OLUWA sọ nípa ìdílé Ahabu yóo ṣẹ. OLUWA ti ṣe ohun tí ó ṣèlérí láti ẹnu Elija, wolii rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:10 ni o tọ