Àwọn Ọba Keji 10:9 BM

9 Ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, Jehu lọ sí ẹnubodè ìlú, ó sì sọ fún àwọn tí wọ́n wà níbẹ̀ pé, “Ẹ kò ní ẹ̀bi, èmi ni mo ṣọ̀tẹ̀ sí Joramu ọba, oluwa mi, tí mo sì pa á. Ṣugbọn ta ni ó pa àwọn wọnyi?

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:9 ni o tọ