Àwọn Ọba Keji 10:8 BM

8 Nígbà tí wọ́n jíṣẹ́ fún Jehu pé wọ́n ti kó orí àwọn ọmọ Ahabu dé, ó pàṣẹ pé kí wọ́n kó wọn jọ sí ọ̀nà meji ní ẹnubodè ìlú, títí di òwúrọ̀ ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:8 ni o tọ