Àwọn Ọba Keji 11:12 BM

12 Lẹ́yìn náà ni ó mú Joaṣi, ọmọ ọba jáde síta, ó fi adé ọba dé e lórí, ó sì fún un ní ìwé òfin. Lẹ́yìn náà ni ó da òróró sí i lórí láti fi jọba. Àwọn eniyan pàtẹ́wọ́, wọ́n sì kígbe pé, “Kabiyesi, kí ẹ̀mí ọba ó gùn!”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:12 ni o tọ