Àwọn Ọba Keji 11:13 BM

13 Nígbà tí Atalaya gbọ́ ariwo àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin ati ti àwọn eniyan, ó jáde lọ sí ilé OLUWA níbi tí àwọn eniyan péjọ sí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:13 ni o tọ