Àwọn Ọba Keji 11:17 BM

17 Jehoiada alufaa mú kí Joaṣi ọba ati àwọn eniyan dá majẹmu pẹlu OLUWA pé àwọn yóo jẹ́ tirẹ̀; ó sì tún mú kí àwọn eniyan náà bá ọba dá majẹmu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:17 ni o tọ